Jeremáyà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo àwọn èèyàn Júdà ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà, ìyẹn ní ọdún kìíní Nebukadinésárì* ọba Bábílónì.
25 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo àwọn èèyàn Júdà ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà, ìyẹn ní ọdún kìíní Nebukadinésárì* ọba Bábílónì.