Jẹ́nẹ́sísì 23:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ábúráhámù gbọ́ ohun tí Éfúrónì sọ, Ábúráhámù sì wọn iye fàdákà tí Éfúrónì sọ níṣojú àwọn ọmọ Hétì fún un, ó jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ṣékélì* fàdákà, ó lo ìwọ̀n tí àwọn oníṣòwò+ ń lò nígbà yẹn.
16 Ábúráhámù gbọ́ ohun tí Éfúrónì sọ, Ábúráhámù sì wọn iye fàdákà tí Éfúrónì sọ níṣojú àwọn ọmọ Hétì fún un, ó jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ṣékélì* fàdákà, ó lo ìwọ̀n tí àwọn oníṣòwò+ ń lò nígbà yẹn.