-
Jeremáyà 51:59Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
59 Ọ̀rọ̀ tí wòlíì Jeremáyà pa láṣẹ fún Seráyà ọmọ Neráyà+ ọmọ Maseáyà nígbà tó bá Sedekáyà ọba Júdà lọ sí Bábílónì ní ọdún kẹrin ìjọba rẹ̀; Seráyà sì ni olórí ibùdó.
-