Jeremáyà 23:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Màá sì gbé àwọn olùṣọ́ àgùntàn dìde lórí wọn tí á máa bójú tó wọn dáadáa.+ Ẹ̀rù ò ní bà wọ́n mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò ní jáyà, kò sì sí ìkankan nínú wọn tó máa sọ nù,” ni Jèhófà wí. Ìsíkíẹ́lì 34:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Èmi yóò yan olùṣọ́ àgùntàn kan fún wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi,+ yóò sì máa bọ́ wọn. Òun fúnra rẹ̀ máa bọ́ wọn, ó sì máa di olùṣọ́ àgùntàn wọn.+
4 Màá sì gbé àwọn olùṣọ́ àgùntàn dìde lórí wọn tí á máa bójú tó wọn dáadáa.+ Ẹ̀rù ò ní bà wọ́n mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò ní jáyà, kò sì sí ìkankan nínú wọn tó máa sọ nù,” ni Jèhófà wí.
23 Èmi yóò yan olùṣọ́ àgùntàn kan fún wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi,+ yóò sì máa bọ́ wọn. Òun fúnra rẹ̀ máa bọ́ wọn, ó sì máa di olùṣọ́ àgùntàn wọn.+