ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 11:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Inú bí Jèhófà gan-an sí Sólómọ́nì, nítorí ọkàn rẹ̀ ti kúrò lọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì,+ ẹni tó fara hàn án lẹ́ẹ̀mejì,+ 10 tí ó sì kìlọ̀ fún un nípa nǹkan yìí pé kí ó má ṣe tẹ̀ lé àwọn ọlọ́run míì.+ Àmọ́ kò ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ.

  • 2 Àwọn Ọba 23:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Síbẹ̀, Jèhófà kò dẹwọ́ ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná lórí Júdà nítorí gbogbo ohun búburú tí Mánásè ti ṣe láti mú un bínú.+

  • 1 Kíróníkà 10:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́