Míkà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí nípa àwọn wòlíì tó ń ṣi àwọn èèyàn mi lọ́nà,+Tí wọ́n ń kéde ‘Àlàáfíà!’+ nígbà tí wọ́n bá ń rí nǹkan jẹ,*+Àmọ́ tí wọ́n ń gbógun ti* ẹni tí kò fún wọn ní nǹkan kan jẹ: Míkà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+ Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé: “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+ Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+
5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí nípa àwọn wòlíì tó ń ṣi àwọn èèyàn mi lọ́nà,+Tí wọ́n ń kéde ‘Àlàáfíà!’+ nígbà tí wọ́n bá ń rí nǹkan jẹ,*+Àmọ́ tí wọ́n ń gbógun ti* ẹni tí kò fún wọn ní nǹkan kan jẹ:
11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+ Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé: “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+ Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+