Jeremáyà 31:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 “Nítorí májẹ̀mú tí màá bá ilé Ísírẹ́lì dá lẹ́yìn ìgbà yẹn nìyí,” ni Jèhófà wí. “Màá fi òfin mi sínú wọn,+ inú ọkàn wọn sì ni màá kọ ọ́ sí.+ Màá di Ọlọ́run wọn, wọ́n á sì di èèyàn mi.”+ Míkà 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Gbogbo èèyàn yóò máa rìn ní orúkọ ọlọ́run wọn,Àmọ́ àwa yóò máa rìn ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa+ títí láé àti láéláé.
33 “Nítorí májẹ̀mú tí màá bá ilé Ísírẹ́lì dá lẹ́yìn ìgbà yẹn nìyí,” ni Jèhófà wí. “Màá fi òfin mi sínú wọn,+ inú ọkàn wọn sì ni màá kọ ọ́ sí.+ Màá di Ọlọ́run wọn, wọ́n á sì di èèyàn mi.”+
5 Gbogbo èèyàn yóò máa rìn ní orúkọ ọlọ́run wọn,Àmọ́ àwa yóò máa rìn ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa+ títí láé àti láéláé.