Ìsíkíẹ́lì 37:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 ‘Èmi yóò fi ẹ̀mí mi sínú yín, ẹ ó sì di alààyè,+ èmi yóò mú kí ẹ máa gbé lórí ilẹ̀ yín; ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀, mo sì ti ṣe é,’ ni Jèhófà wí.”
14 ‘Èmi yóò fi ẹ̀mí mi sínú yín, ẹ ó sì di alààyè,+ èmi yóò mú kí ẹ máa gbé lórí ilẹ̀ yín; ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀, mo sì ti ṣe é,’ ni Jèhófà wí.”