Àìsáyà 53:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó máa jáde wá bí ẹ̀ka igi+ níwájú rẹ̀,* bíi gbòǹgbò látinú ilẹ̀ tó gbẹ táútáú. Ìrísí rẹ̀ kò buyì kún un, kò sì rẹwà rárá;+Tí a bá sì rí i, ìrísí rẹ̀ kò fà wá sún mọ́ ọn.* Sekaráyà 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí o sì sọ fún un pé,“‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Èéhù+ rèé. Yóò hù jáde láti àyè rẹ̀, yóò sì kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà.+ Ìfihàn 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+
2 Ó máa jáde wá bí ẹ̀ka igi+ níwájú rẹ̀,* bíi gbòǹgbò látinú ilẹ̀ tó gbẹ táútáú. Ìrísí rẹ̀ kò buyì kún un, kò sì rẹwà rárá;+Tí a bá sì rí i, ìrísí rẹ̀ kò fà wá sún mọ́ ọn.*
12 Kí o sì sọ fún un pé,“‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Èéhù+ rèé. Yóò hù jáde láti àyè rẹ̀, yóò sì kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà.+
16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+