2 Àwọn Ọba 25:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Lẹ́yìn náà, wọ́n gbá ọba mú,+ wọ́n mú un wá sọ́dọ̀ ọba Bábílónì ní Ríbúlà, wọ́n sì dá a lẹ́jọ́. 7 Wọ́n pa àwọn ọmọ Sedekáyà níṣojú rẹ̀; Nebukadinésárì wá fọ́ ojú Sedekáyà, ó fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ bàbà dè é, ó sì mú un wá sí Bábílónì.+ Ìdárò 4:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Èémí wa, ẹni àmì òróró Jèhófà,+ ni wọ́n ti mú nínú kòtò ńlá wọn,+Ẹni tí a sọ nípa rẹ̀ pé: “Abẹ́ òjìji rẹ̀ la ó máa gbé láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.”
6 Lẹ́yìn náà, wọ́n gbá ọba mú,+ wọ́n mú un wá sọ́dọ̀ ọba Bábílónì ní Ríbúlà, wọ́n sì dá a lẹ́jọ́. 7 Wọ́n pa àwọn ọmọ Sedekáyà níṣojú rẹ̀; Nebukadinésárì wá fọ́ ojú Sedekáyà, ó fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ bàbà dè é, ó sì mú un wá sí Bábílónì.+
20 Èémí wa, ẹni àmì òróró Jèhófà,+ ni wọ́n ti mú nínú kòtò ńlá wọn,+Ẹni tí a sọ nípa rẹ̀ pé: “Abẹ́ òjìji rẹ̀ la ó máa gbé láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.”