-
Jeremáyà 4:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ẹ ròyìn rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni, ẹ ròyìn rẹ̀ fún àwọn orílẹ̀-èdè;
Ẹ kéde rẹ̀ sórí Jerúsálẹ́mù.”
“Àwọn ẹ̀ṣọ́* ń bọ̀ láti ilẹ̀ tó jìnnà,
Wọ́n á sì gbé ohùn wọn sókè sí àwọn ìlú Júdà.
-
-
Jeremáyà 32:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 “‘Nítorí pé kìkì ohun tó burú lójú mi ni àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti ti Júdà ń ṣe láti ìgbà èwe wọn wá;+ ńṣe ni àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ń fi iṣẹ́ ọwọ́ wọn mú mi bínú,’ ni Jèhófà wí.
-