-
Jeremáyà 7:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà bá Jeremáyà sọ nìyí, ó ní: 2 “Dúró sí ẹnubodè ilé Jèhófà, kí o sì kéde ọ̀rọ̀ yìí níbẹ̀ pé, ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin èèyàn Júdà tó ń gba àwọn ẹnubodè yìí wọlé láti wá forí balẹ̀ fún Jèhófà.
-