-
Jeremáyà 36:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Lẹ́yìn náà, wọ́n wọlé lọ bá ọba ní àgbàlá, wọ́n fi àkájọ ìwé náà sí yàrá ìjẹun Élíṣámà akọ̀wé, wọ́n sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí wọ́n gbọ́ náà fún ọba.
-