- 
	                        
            
            Jeremáyà 36:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Ìgbà náà ni gbogbo àwọn ìjòyè rán Jéhúdì ọmọ Netanáyà ọmọ Ṣelemáyà ọmọ Kúúṣì sí Bárúkù pé: “Wá, kí o sì mú àkájọ ìwé tí o kà ní etí àwọn èèyàn náà dání.” Bárúkù ọmọ Neráyà mú àkájọ ìwé náà dání, ó sì wọlé lọ bá wọn. 
 
-