Hósíà 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Mo rí Ísírẹ́lì bí ẹni rí èso àjàrà ní aginjù.+ Mo rí àwọn baba ńlá rẹ̀ bí ẹni rí àkọ́so igi ọ̀pọ̀tọ́. Àmọ́ wọ́n lọ bá Báálì Péórì;+Wọ́n fi ara wọn fún ohun ìtìjú,*+Wọ́n di ohun ìríra, wọ́n sì wá dà bí ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́.
10 “Mo rí Ísírẹ́lì bí ẹni rí èso àjàrà ní aginjù.+ Mo rí àwọn baba ńlá rẹ̀ bí ẹni rí àkọ́so igi ọ̀pọ̀tọ́. Àmọ́ wọ́n lọ bá Báálì Péórì;+Wọ́n fi ara wọn fún ohun ìtìjú,*+Wọ́n di ohun ìríra, wọ́n sì wá dà bí ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́.