-
Jeremáyà 36:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Lẹ́yìn tí Jéhúdì bá ti ka abala mẹ́ta tàbí mẹ́rin, ọba á fi ọ̀bẹ akọ̀wé gé apá ibẹ̀ dà nù, á sì sọ ọ́ sínú iná tó ń jó nínú àdògán náà, ó ṣe bẹ́ẹ̀ títí tó fi sọ gbogbo àkájọ ìwé náà sínú iná àdògán.
-