Jeremáyà 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ègún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn lásánlàsàn,+Tó gbára lé agbára èèyàn,*+Tí ọkàn rẹ̀ sì pa dà lẹ́yìn Jèhófà. Ìdárò 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kódà ní báyìí, ojú wa ti di bàìbàì bí a ṣe ń retí ìrànwọ́ tí kò sì dé.+ A wá ìrànwọ́ títí lọ́dọ̀ orílẹ̀-èdè tí kò lè gbà wá.+ Ìsíkíẹ́lì 17:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹgbẹ́ ogun Fáráò àti àwọn ọmọ ogun wọn kò ní lè ràn wọ́n lọ́wọ́ nígbà ogun,+ nígbà tí wọ́n bá mọ òkìtì láti dó tì í, tí wọ́n sì mọ odi kí wọ́n lè gbẹ̀mí ọ̀pọ̀ èèyàn.*
5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ègún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn lásánlàsàn,+Tó gbára lé agbára èèyàn,*+Tí ọkàn rẹ̀ sì pa dà lẹ́yìn Jèhófà.
17 Kódà ní báyìí, ojú wa ti di bàìbàì bí a ṣe ń retí ìrànwọ́ tí kò sì dé.+ A wá ìrànwọ́ títí lọ́dọ̀ orílẹ̀-èdè tí kò lè gbà wá.+
17 Ẹgbẹ́ ogun Fáráò àti àwọn ọmọ ogun wọn kò ní lè ràn wọ́n lọ́wọ́ nígbà ogun,+ nígbà tí wọ́n bá mọ òkìtì láti dó tì í, tí wọ́n sì mọ odi kí wọ́n lè gbẹ̀mí ọ̀pọ̀ èèyàn.*