-
1 Àwọn Ọba 17:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àwọn ẹyẹ ìwò ń gbé búrẹ́dì àti ẹran wá fún un ní àárọ̀, wọ́n tún ń gbé búrẹ́dì àti ẹran wá fún un ní ìrọ̀lẹ́, ó sì ń mu omi láti inú odò náà.+
-