Àìsáyà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti búra ní etí mi,Pé ọ̀pọ̀ ilé, bí wọ́n tiẹ̀ tóbi, tí wọ́n sì rẹwà,Wọ́n máa di ohun àríbẹ̀rù,Láìsí olùgbé kankan.+ Jeremáyà 38:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́, bí o kò bá fi ara rẹ lé* àwọn ìjòyè ọba Bábílónì lọ́wọ́, a ó fa ìlú yìí lé àwọn ará Kálídíà lọ́wọ́, wọ́n á dáná sun ún,+ o ò sì ní lè sá mọ́ wọn lọ́wọ́.’”+
9 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti búra ní etí mi,Pé ọ̀pọ̀ ilé, bí wọ́n tiẹ̀ tóbi, tí wọ́n sì rẹwà,Wọ́n máa di ohun àríbẹ̀rù,Láìsí olùgbé kankan.+
18 Àmọ́, bí o kò bá fi ara rẹ lé* àwọn ìjòyè ọba Bábílónì lọ́wọ́, a ó fa ìlú yìí lé àwọn ará Kálídíà lọ́wọ́, wọ́n á dáná sun ún,+ o ò sì ní lè sá mọ́ wọn lọ́wọ́.’”+