ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 25:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Nebukadinésárì ọba Bábílónì yan Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ṣe olórí àwọn èèyàn tí ó fi sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà.+

  • Jeremáyà 40:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Kí Jeremáyà tó pẹ̀yìn dà, Nebusarádánì sọ pé: “Pa dà sọ́dọ̀ Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì,+ ẹni tí ọba Bábílónì yàn ṣe olórí àwọn ìlú Júdà, sì máa gbé pẹ̀lú rẹ̀ ní àárín àwọn èèyàn náà tàbí kí o lọ sí ibikíbi tí o bá fẹ́.”

      Olórí ẹ̀ṣọ́ wá fún un ní oúnjẹ díẹ̀ àti ẹ̀bùn, ó sì jẹ́ kó máa lọ.

  • Jeremáyà 41:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà àti àwọn ọkùnrin mẹ́wàá tó wà pẹ̀lú rẹ̀ dìde, wọ́n sì fi idà pa Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù ọmọ Ṣáfánì. Nípa bẹ́ẹ̀, ó pa ẹni tí ọba Bábílónì yàn ṣe olórí ilẹ̀ náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́