2 Àwọn Ọba 25:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nebukadinésárì ọba Bábílónì yan Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ṣe olórí àwọn èèyàn tí ó fi sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà.+ Jeremáyà 39:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ fi lára àwọn aláìní sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà, àwọn tí kò ní nǹkan kan. Lọ́jọ́ yẹn, ó tún fún wọn ní ọgbà àjàrà àti oko láti máa ṣiṣẹ́.*+
22 Nebukadinésárì ọba Bábílónì yan Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ṣe olórí àwọn èèyàn tí ó fi sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà.+
10 Àmọ́ Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ fi lára àwọn aláìní sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà, àwọn tí kò ní nǹkan kan. Lọ́jọ́ yẹn, ó tún fún wọn ní ọgbà àjàrà àti oko láti máa ṣiṣẹ́.*+