Jeremáyà 35:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ nígbà tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì wá gbéjà ko ilẹ̀ tí à ń gbé,+ a sọ pé, ‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a wọnú Jerúsálẹ́mù kí a má bàa bọ́ sọ́wọ́ àwọn ọmọ ogun Kálídíà àti ti Síríà.’ Bó ṣe di pé à ń gbé Jerúsálẹ́mù nìyẹn.”
11 Àmọ́ nígbà tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì wá gbéjà ko ilẹ̀ tí à ń gbé,+ a sọ pé, ‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a wọnú Jerúsálẹ́mù kí a má bàa bọ́ sọ́wọ́ àwọn ọmọ ogun Kálídíà àti ti Síríà.’ Bó ṣe di pé à ń gbé Jerúsálẹ́mù nìyẹn.”