Jeremáyà 40:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n sọ fún un pé: “Ṣé o kò mọ̀ pé Báálísì, ọba àwọn ọmọ Ámónì,+ ti rán Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà láti wá pa ọ́?”*+ Ṣùgbọ́n Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù kò gbà wọ́n gbọ́.
14 Wọ́n sọ fún un pé: “Ṣé o kò mọ̀ pé Báálísì, ọba àwọn ọmọ Ámónì,+ ti rán Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà láti wá pa ọ́?”*+ Ṣùgbọ́n Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù kò gbà wọ́n gbọ́.