Ìsíkíẹ́lì 26:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò mú kí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì gbéjà ko Tírè láti àríwá;+ ọba àwọn ọba ni,+ pẹ̀lú àwọn ẹṣin,+ kẹ̀kẹ́ ogun,+ àwọn tó ń gẹṣin àti ọ̀pọ̀ ọmọ ogun.*
7 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò mú kí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì gbéjà ko Tírè láti àríwá;+ ọba àwọn ọba ni,+ pẹ̀lú àwọn ẹṣin,+ kẹ̀kẹ́ ogun,+ àwọn tó ń gẹṣin àti ọ̀pọ̀ ọmọ ogun.*