Jeremáyà 44:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣe ni màá fìyà jẹ àwọn tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì, bí mo ṣe fìyà jẹ Jerúsálẹ́mù nípasẹ̀ idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn.*+ Ìsíkíẹ́lì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àjàkálẹ̀ àrùn* tàbí ìyàn máa pa ìdá mẹ́ta lára yín. Wọ́n á sì fi idà pa ìdá mẹ́ta míì láyìíká yín.+ Màá fọ́n ìdá mẹ́ta yòókù káàkiri,* màá sì fa idà yọ láti fi lé wọn.+
13 Ṣe ni màá fìyà jẹ àwọn tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì, bí mo ṣe fìyà jẹ Jerúsálẹ́mù nípasẹ̀ idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn.*+
12 Àjàkálẹ̀ àrùn* tàbí ìyàn máa pa ìdá mẹ́ta lára yín. Wọ́n á sì fi idà pa ìdá mẹ́ta míì láyìíká yín.+ Màá fọ́n ìdá mẹ́ta yòókù káàkiri,* màá sì fa idà yọ láti fi lé wọn.+