ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 46:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Sọ ọ́ ní Íjíbítì, sì kéde rẹ̀ ní Mígídólì.+

      Kéde rẹ̀ ní Nófì* àti ní Tápánẹ́sì.+

      Sọ pé, ‘Ẹ dúró sí àyè yín, kí ẹ sì múra sílẹ̀,

      Nítorí idà kan máa pani run ní gbogbo àyíká yín.

  • Ìsíkíẹ́lì 30:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Màá dá iná sí Íjíbítì; ìbẹ̀rù á bo Sínì, wọ́n á ya wọ Nóò, wọ́n á sì gbógun ti Nófì* ní ojúmọmọ!

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́