Ìsíkíẹ́lì 27:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ní tìrẹ, ọmọ èèyàn, kọ orin arò* nípa Tírè,+ Ìsíkíẹ́lì 27:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ará Páṣíà, Lúdì àti Pútì+ wà lára àwọn jagunjagun rẹ, àwọn ọkùnrin ogun rẹ. Inú rẹ ni wọ́n gbé apata àti akoto* wọn kọ́ sí, wọ́n sì ṣe ọ́ lógo.
10 Àwọn ará Páṣíà, Lúdì àti Pútì+ wà lára àwọn jagunjagun rẹ, àwọn ọkùnrin ogun rẹ. Inú rẹ ni wọ́n gbé apata àti akoto* wọn kọ́ sí, wọ́n sì ṣe ọ́ lógo.