-
Ìsíkíẹ́lì 32:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 ‘Èmi yóò mú kí ìdààmú bá ọkàn ọ̀pọ̀ èèyàn nígbà tí mo bá mú àwọn èèyàn rẹ tí wọ́n kó lẹ́rú lọ sí àwọn orílẹ̀-èdè míì,
Lọ sí àwọn ilẹ̀ tí o kò mọ̀.+
-