Àìsáyà 5:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ó ti gbé àmì sókè* sí orílẹ̀-èdè tó wà lọ́nà jíjìn;+Ó ti súfèé sí wọn pé kí wọ́n wá láti àwọn ìkángun ayé;+Sì wò ó! wọ́n ń yára bọ̀.+ Àìsáyà 5:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Gbogbo ọfà wọn mú,Wọ́n sì ti fa gbogbo ọrun wọn.* Pátákò àwọn ẹṣin wọn dà bí akọ òkúta, Àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ wọn sì dà bí ìjì.+
26 Ó ti gbé àmì sókè* sí orílẹ̀-èdè tó wà lọ́nà jíjìn;+Ó ti súfèé sí wọn pé kí wọ́n wá láti àwọn ìkángun ayé;+Sì wò ó! wọ́n ń yára bọ̀.+
28 Gbogbo ọfà wọn mú,Wọ́n sì ti fa gbogbo ọrun wọn.* Pátákò àwọn ẹṣin wọn dà bí akọ òkúta, Àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ wọn sì dà bí ìjì.+