-
Jeremáyà 46:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 ‘Kí nìdí tí mo fi rí wọn tí jìnnìjìnnì bò wọ́n?
Wọ́n ń sá pa dà, àwọn jagunjagun wọn ni a ti lù bolẹ̀.
Wọ́n ti sá lọ tẹ̀rùtẹ̀rù, àwọn jagunjagun wọn kò sì bojú wẹ̀yìn.
Ìbẹ̀rù wà níbi gbogbo,’ ni Jèhófà wí.
-
-
Jeremáyà 46:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Kí nìdí tí a fi gbá àwọn alágbára ọkùnrin yín lọ?
Wọn kò lè dúró,
Nítorí Jèhófà ti tì wọ́n ṣubú.
-