-
Jeremáyà 17:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
-
-
Jeremáyà 42:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 tí ẹ sọ pé, “Rárá o, kàkà bẹ́ẹ̀, ilẹ̀ Íjíbítì ni a máa lọ,+ níbi tí a ò ti ní rí ogun, tí a ò ní gbọ́ ìró ìwo, tí ebi kò sì ní pa wá; ibẹ̀ sì ni a ó máa gbé,”
-