ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 5:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Ẹ wá sí pooro* oko àjàrà rẹ̀, kí ẹ sì bà á jẹ́,

      Ṣùgbọ́n ẹ má pa á run.+

      Ẹ gé àwọn ẹ̀ka rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ yọ,

      Nítorí wọn kì í ṣe ti Jèhófà.

  • Émọ́sì 9:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 ‘Wò ó! Ojú Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára ìjọba tó ń dẹ́ṣẹ̀,

      Á sì pa á rẹ́ kúrò lórí ilẹ̀.+

      Ṣùgbọ́n, mi ò ní pa gbogbo ilé Jékọ́bù rẹ́,’+ ni Jèhófà wí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́