Àìsáyà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ wẹ ara yín, ẹ jẹ́ kí ara yín mọ́;+Ẹ mú ìwà ibi yín kúrò níwájú mi;Ẹ jáwọ́ nínú ìwà burúkú.+ Ìsíkíẹ́lì 18:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹ jáwọ́ nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín,+ kí ẹ sì ní* ọkàn tuntun àti ẹ̀mí tuntun.+ Ṣé ó wá yẹ kí ẹ kú,+ ilé Ísírẹ́lì?’
31 Ẹ jáwọ́ nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín,+ kí ẹ sì ní* ọkàn tuntun àti ẹ̀mí tuntun.+ Ṣé ó wá yẹ kí ẹ kú,+ ilé Ísírẹ́lì?’