Jẹ́nẹ́sísì 10:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,+ 14 Pátírúsímù,+ Kásílúhímù (ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn Filísínì+ ti wá) àti Káfítórímù.+ Diutarónómì 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ní ti àwọn Áfímù, ibi tí wọ́n ń gbé nasẹ̀ dé Gásà,+ títí àwọn Káfítórímù tí wọ́n wá láti Káfítórì*+ fi pa wọ́n run, tí wọ́n sì ń gbé ilẹ̀ wọn.)
13 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,+ 14 Pátírúsímù,+ Kásílúhímù (ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn Filísínì+ ti wá) àti Káfítórímù.+
23 Ní ti àwọn Áfímù, ibi tí wọ́n ń gbé nasẹ̀ dé Gásà,+ títí àwọn Káfítórímù tí wọ́n wá láti Káfítórì*+ fi pa wọ́n run, tí wọ́n sì ń gbé ilẹ̀ wọn.)