- 
	                        
            
            Sefanáyà 2:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Nítorí náà, bí mo ti wà láàyè,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí, “Móábù máa dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,+ Àti àwọn ọmọ Ámónì bíi Gòmórà,+ Ibi tí èsìsì wà, tí kòtò iyọ̀ wà, tó sì ti di ahoro títí láé.+ Àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn mi á kó wọn lọ, Àwọn tó ṣẹ́ kù nínú orílẹ̀-èdè mi á sì gba tọwọ́ wọn. 
 
-