Àìsáyà 34:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí Jèhófà ń bínú sí gbogbo orílẹ̀-èdè,+Inú rẹ̀ sì ń ru sí gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn.+ Ó máa pa wọ́n run;Ó máa pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ.+
2 Torí Jèhófà ń bínú sí gbogbo orílẹ̀-èdè,+Inú rẹ̀ sì ń ru sí gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn.+ Ó máa pa wọ́n run;Ó máa pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ.+