Jeremáyà 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Màá fòpin sí ìró ayọ̀ àti ìró ìdùnnú láàárín wọn,+ màá sì tún fòpin sí ohùn ọkọ ìyàwó àti ohùn ìyàwó,+ ìró ọlọ àti ìmọ́lẹ̀ fìtílà.
10 Màá fòpin sí ìró ayọ̀ àti ìró ìdùnnú láàárín wọn,+ màá sì tún fòpin sí ohùn ọkọ ìyàwó àti ohùn ìyàwó,+ ìró ọlọ àti ìmọ́lẹ̀ fìtílà.