Sefanáyà 1:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọjọ́ yẹn jẹ́ ọjọ́ ìbínú ńlá,+Ọjọ́ wàhálà àti ìdààmú,+Ọjọ́ ìjì àti ìsọdahoro,Ọjọ́ òkùnkùn àti ìṣúdùdù,+Ọjọ́ ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà,+16 Ọjọ́ ìwo àti ariwo ogun,+Lòdì sí àwọn ìlú olódi àti sí àwọn ilé gogoro tó wà ní àwọn ìkángun odi.+
15 Ọjọ́ yẹn jẹ́ ọjọ́ ìbínú ńlá,+Ọjọ́ wàhálà àti ìdààmú,+Ọjọ́ ìjì àti ìsọdahoro,Ọjọ́ òkùnkùn àti ìṣúdùdù,+Ọjọ́ ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà,+16 Ọjọ́ ìwo àti ariwo ogun,+Lòdì sí àwọn ìlú olódi àti sí àwọn ilé gogoro tó wà ní àwọn ìkángun odi.+