-
Jeremáyà 16:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àti ẹni ńlá àti ẹni kékeré, gbogbo wọn ni yóò kú ní ilẹ̀ yìí.
A kò ní sin wọ́n,
Ẹnì kankan ò ní ṣọ̀fọ̀ wọn,
Bẹ́ẹ̀ ni ẹnì kankan ò ní fi abẹ kọ ara rẹ̀ tàbí kó mú orí ara rẹ̀ pá nítorí wọn.*
-