- 
	                        
            
            Ìsíkíẹ́lì 25:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Èmi yóò sọ Rábà+ di ibi tí àwọn ràkúnmí á ti máa jẹko, èmi yóò sì sọ ilẹ̀ àwọn ọmọ Ámónì di ibi ìsinmi agbo ẹran; ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.”’” 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Émọ́sì 1:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Torí náà, màá sọ iná sí ògiri Rábà,+ Á sì jó àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò run, Ariwo á sọ ní ọjọ́ ogun, Àti ìjì líle ní ọjọ́ ẹ̀fúùfù. 
 
-