Ọbadáyà 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Bí àwọn olè bá wá bá ọ, àwọn ọlọ́ṣà ní òru,(Ṣe ni wọ́n á run ọ́!)* Ṣebí ohun tí wọ́n bá fẹ́ nìkan ni wọ́n á kó? Tó bá sì jẹ́ àwọn tó ń kó èso àjàrà jọ ló wá bá ọ,Ṣé wọn ò ní ṣẹ́ díẹ̀ kù fáwọn tó ń pèéṣẹ́?*+
5 “Bí àwọn olè bá wá bá ọ, àwọn ọlọ́ṣà ní òru,(Ṣe ni wọ́n á run ọ́!)* Ṣebí ohun tí wọ́n bá fẹ́ nìkan ni wọ́n á kó? Tó bá sì jẹ́ àwọn tó ń kó èso àjàrà jọ ló wá bá ọ,Ṣé wọn ò ní ṣẹ́ díẹ̀ kù fáwọn tó ń pèéṣẹ́?*+