- 
	                        
            
            Ọbadáyà 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        18 Ilé Jékọ́bù yóò di iná, Ilé Jósẹ́fù yóò di ọwọ́ iná, Ilé Ísọ̀ yóò sì dà bí àgékù pòròpórò; Wọn yóò ti iná bọ̀ wọ́n, wọn yóò sì run wọ́n, Ẹnikẹ́ni kì yóò sì là á já ní ilé Ísọ̀,+ Torí Jèhófà fúnra rẹ̀ ti sọ ọ́. 
 
-