ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 13:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Torí náà, wọ́n gòkè lọ, wọ́n sì ṣe amí ilẹ̀ náà láti aginjù Síínì+ dé Réhóbù+ ní tòsí Lebo-hámátì.*+

  • 2 Àwọn Ọba 17:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Lẹ́yìn náà, ọba Ásíríà kó àwọn èèyàn wá láti Bábílónì, Kútà, Áfà, Hámátì àti Séfáfáímù,+ ó sì ní kí wọ́n máa gbé inú àwọn ìlú Samáríà níbi tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé tẹ́lẹ̀; wọ́n gba Samáríà, wọ́n sì ń gbé inú àwọn ìlú rẹ̀.

  • Sekaráyà 9:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ìkéde:

      “Jèhófà bá ilẹ̀ Hádírákì wí,

      Damásíkù gangan ni ọ̀rọ̀ náà kàn,*+

      Torí ojú Jèhófà wà lára aráyé+

      Àti lára gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì.

       2 Ọ̀rọ̀ náà tún kan Hámátì+ tí wọ́n jọ pààlà

      Àti Tírè+ pẹ̀lú Sídónì,+ torí wọ́n gbọ́n féfé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́