Émọ́sì 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí náà, màá rán iná sí ilé Hásáẹ́lì,+Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ti Bẹni-hádádì run.+