Àìsáyà 22:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Élámù+ gbé apó,Pẹ̀lú àwọn tó ń gun kẹ̀kẹ́ ogun àtàwọn ẹṣin,*Kírì+ sì ṣí* apata.