Àìsáyà 53:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Gbogbo wa ti rìn gbéregbère bí àgùntàn,+Kálukú ti yíjú sí ọ̀nà tirẹ̀,Jèhófà sì ti mú kó ru ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo wa.+
6 Gbogbo wa ti rìn gbéregbère bí àgùntàn,+Kálukú ti yíjú sí ọ̀nà tirẹ̀,Jèhófà sì ti mú kó ru ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo wa.+