Sáàmù 79:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Da ìrunú rẹ sórí àwọn orílẹ̀-èdè tí kò mọ̀ ọ́Àti sórí àwọn ìjọba tí kì í ké pe orúkọ rẹ.+ 7 Nítorí wọ́n ti jẹ Jékọ́bù run,Wọ́n sì ti sọ ìlú ìbílẹ̀ rẹ̀ di ahoro.+
6 Da ìrunú rẹ sórí àwọn orílẹ̀-èdè tí kò mọ̀ ọ́Àti sórí àwọn ìjọba tí kì í ké pe orúkọ rẹ.+ 7 Nítorí wọ́n ti jẹ Jékọ́bù run,Wọ́n sì ti sọ ìlú ìbílẹ̀ rẹ̀ di ahoro.+