Àìsáyà 47:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Inú bí mi sí àwọn èèyàn mi.+ Mo sọ ogún mi di aláìmọ́,+Mo sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Àmọ́ o ò ṣàánú wọn rárá.+ Kódà, o gbé àjàgà tó wúwo lé àgbàlagbà.+
6 Inú bí mi sí àwọn èèyàn mi.+ Mo sọ ogún mi di aláìmọ́,+Mo sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Àmọ́ o ò ṣàánú wọn rárá.+ Kódà, o gbé àjàgà tó wúwo lé àgbàlagbà.+