Àìsáyà 41:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Má bẹ̀rù, ìwọ Jékọ́bù kòkòrò mùkúlú,*+Ẹ̀yin ọkùnrin Ísírẹ́lì, màá ràn yín lọ́wọ́,” ni Jèhófà, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì wí. Ìfihàn 18:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìdí nìyẹn tí àwọn ìyọnu rẹ̀ fi máa dé ní ọjọ́ kan ṣoṣo, ikú àti ọ̀fọ̀ àti ìyàn, a sì máa fi iná sun ún pátápátá,+ torí pé Jèhófà* Ọlọ́run, ẹni tó ṣèdájọ́ rẹ̀, jẹ́ alágbára.+
14 Má bẹ̀rù, ìwọ Jékọ́bù kòkòrò mùkúlú,*+Ẹ̀yin ọkùnrin Ísírẹ́lì, màá ràn yín lọ́wọ́,” ni Jèhófà, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì wí.
8 Ìdí nìyẹn tí àwọn ìyọnu rẹ̀ fi máa dé ní ọjọ́ kan ṣoṣo, ikú àti ọ̀fọ̀ àti ìyàn, a sì máa fi iná sun ún pátápátá,+ torí pé Jèhófà* Ọlọ́run, ẹni tó ṣèdájọ́ rẹ̀, jẹ́ alágbára.+