Àìsáyà 14:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní ọjọ́ tí Jèhófà bá mú kí o bọ́ nínú ìrora rẹ, rúkèrúdò rẹ àti bí wọ́n ṣe ń fipá mú ọ sìnrú,+ 4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé: “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́! Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+
3 Ní ọjọ́ tí Jèhófà bá mú kí o bọ́ nínú ìrora rẹ, rúkèrúdò rẹ àti bí wọ́n ṣe ń fipá mú ọ sìnrú,+ 4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé: “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́! Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+